Skip to content

Yoruba Bible

Mika 4:5

Nitori gbogbo awọn enia ni yio ma rìn, olukuluku li orukọ ọlọrun tirẹ̀, awa o si ma rìn li orukọ Oluwa Ọlọrun wa lai ati lailai. Israẹli Yóo Pada láti Oko Ẹrú

Open Bible reader