Skip to content

Yoruba Bible

Marku 9:1

O si wi fun wọn pe, Lõtọ ni mo wi fun nyin, Ẹlomiran wà ninu awọn ti o duro nihinyi, ti kì yio tọ́ iku wò, titi nwọn o fi ri ti ijọba Ọlọrun yio fi de pẹlu agbara. Jesu Para Dà lórí Òkè (Mat 17:1-13; Luk 9:28-36)

Open Bible reader