DaBible
Malachi 3:12
Yoruba
Gbogbo orilẹ-ède ni yio si pè nyin li alabukún fun: nitori ẹnyin o jẹ ilẹ ti o wuni, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi. Ìlérí Àánú Tí Ọlọrun Ṣe
English / KJV
And all nations shall call you blessed: for ye shall be a delightsome land, saith the LORD of hosts.