DaBible
Luke 9:17
Yoruba
Nwọn si jẹ, gbogbo wọn si yó: nwọn ṣà agbọ̀n mejila jọ ninu ajẹkù ti o kù fun wọn. Peteru Jẹ́wọ́ Ẹni Tí Jesu Í Ṣe (Mat 16:13-19; Mak 8:27-29)
English / KJV
And they did eat, and were all filled: and there was taken up of fragments that remained to them twelve baskets.