Yoruba Bible
Luku 8:18
Njẹ ki ẹnyin ki o mã kiyesara bi ẹnyin ti ngbọ́: nitori ẹnikẹni ti o ba ni, on li a o fifun; ati ẹnikẹni ti kò ba si ni, lọwọ rẹ̀ li a o si gbà eyi ti o ṣebi on ni. Ìyá ati Àwọn Arakunrin Jesu (Mat 12:46-50; Mak 3:31-35)
Open Bible reader