Skip to content

DaBible

Luke 8:10

Yoruba

O si wi fun wọn pe, Ẹnyin li a fifun lati mọ̀ ọ̀rọ ijinlẹ ijọba Ọlọrun: ṣugbọn fun awọn miran li owe; pe ni riri, ki nwọn ki o má le ri, ati ni gbigbọ ki o má le yé wọn. Jesu Ṣe Àlàyé Òwe Nípa Afunrugbin (Mat 13:18-23; Mak 4:13-20)

English / KJV

And he said, Unto you it is given to know the mysteries of the kingdom of God: but to others in parables; that seeing they might not see, and hearing they might not understand.

Download DaBible

Read online