Skip to content

Yoruba Bible

Onidajo 1:26

Ọkunrin na si lọ si ilẹ awọn Hitti, o si tẹ̀ ilu kan dó, o si pè orukọ rẹ̀ ni Lusi: eyi si li orukọ rẹ̀ titi di oni. Àwọn Tí Àwọn Ọmọ Israẹli Kò Lé Jáde

Open Bible reader