Skip to content

Yoruba Bible

Joshua 13:23

Ati àla awọn ọmọ Reubeni ni Jordani, ati àgbegbe rẹ̀. Eyi ni ilẹ iní awọn ọmọ Reubeni gẹgẹ bi idile wọn, awọn ilu ati ileto wọn. Ilẹ̀ Tí Wọ́n Pín fún Ẹ̀yà Gadi

Open Bible reader