Skip to content

Yoruba Bible

Joshua 10:27

O si ṣe li akokò ìwọ-õrùn, Joṣua paṣẹ, nwọn si sọ̀ wọn kalẹ kuro lori igi, nwọn si gbé wọn s sinu ihò na ninu eyiti nwọn ti sapamọ́ si, nwọn si fi okuta nla di ẹnu ihò na, ti o wà titi di oni-oloni. Joṣua Tún Gba Àwọn Ìlú Amori Mìíràn Sí i

Open Bible reader