Skip to content

Yoruba Bible

Johannu 3:21

Ṣugbọn ẹniti o ba nṣe otitọ ni iwá si imọlẹ, ki iṣẹ rẹ̀ ki o le fi ara hàn pe, a ṣe wọn nipa ti Ọlọrun. Johanu Tún Sọ̀rọ̀ nípa Jesu

Open Bible reader