Skip to content

Yoruba Bible

Johannu 12:26

Bi ẹnikẹni ba nsìn mi, ki o ma tọ̀ mi lẹhin: ati nibiti emi ba wà, nibẹ̀ ni iranṣẹ mi yio wà pẹlu: bi ẹnikẹni ba nsìn mi, on ni Baba yio bù ọlá fun. A Níláti Gbé Ọmọ-Eniyan Sókè

Open Bible reader