DaBible
John 11:44
Yoruba
Ẹniti o kú na si jade wá, ti a fi aṣọ okú dì tọwọ tẹsẹ a si fi gèle dì i loju. Jesu wi fun wọn pe, Ẹ tú u, ẹ si jẹ ki o mã lọ. Àwọn Juu Dìtẹ̀ láti Pa Jesu (Mat 26:1-5; Mak 14:1-2; Luk 22:1-2)
English / KJV
And he that was dead came forth, bound hand and foot with graveclothes: and his face was bound about with a napkin. Jesus saith unto them, Loose him, and let him go.