Skip to content

Yoruba Bible

Jobu 1:12

Oluwa si dá Satani lohùn wipe: kiyesi i, ohun gbogbo ti o ni mbẹ ni ikawọ rẹ, kìki on tikara rẹ̀ ni iwọ kò gbọdọ̀ fi ọwọ rẹ kàn: bẹ̃ni Satani jade lọ kuro niwaju Oluwa. Ọrọ̀ ati Àwọn Ọmọ Jobu Parun

Open Bible reader