Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 50:20

Li ọjọ wọnni, ati li akoko na, li Oluwa wi, a o wá aiṣedẽde Israeli kiri, ṣugbọn kì o si mọ́; ati ẹ̀ṣẹ Juda, a kì o si ri wọn: nitori emi o dariji awọn ti mo mu ṣẹkù. Ìdájọ́ Ọlọrun lórí Babiloni

Open Bible reader