Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 4:22

Nitori òpe li enia mi, nwọn kò mọ̀ mi; alaimoye ọmọ ni nwọn iṣe, nwọn kò si ni ìmọ: nwọn ni ọgbọ́n lati ṣe ibi, ṣugbọn oye ati ṣe rere ni nwọn kò ni. Ìran tí Jeremiah Rí nípa Ìparun Tí Ń Bọ̀

Open Bible reader