Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 34:7

Ni wakati na ogun ọba Babeli mba Jerusalemu jà, ati gbogbo ilu Juda ti o kù, Lakiṣi, ati Aseka: wọnyi li o kù ninu ilu Juda, nitori nwọn jẹ ilu olodi. Wọ́n Rẹ́ Àwọn Ẹrú Jẹ

Open Bible reader