Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 3:18

Li ọjọ wọnnì, ile Juda yio rin pẹlu ile Israeli, nwọn o jumọ wá lati ilẹ ariwa, si ilẹ ti emi ti fi fun awọn baba nyin li ogún. Ìbọ̀rìṣà Àwọn Eniyan Ọlọrun

Open Bible reader