Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 25:14

Nitoriti awọn wọnyi pẹlu yio mu ki orilẹ-ède pupọ, ati awọn ọba nla sìn wọn: emi o san a fun wọn gẹgẹ bi iṣe wọn ati pẹlu gẹgẹ bi iṣẹ ọwọ wọn. Ìdájọ́ OLUWA lórí Àwọn Orílẹ̀-èdè náà

Open Bible reader