Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 13:14

Emi o tì ekini lu ekeji, ani awọn baba ati awọn ọmọkunrin pọ̀, li Oluwa wi: emi kì yio dariji, bẹ̃ni emi kì o ṣãnu, emi kì yio ṣe iyọ́nu, lati má pa wọn run. Jeremiah ṣe Ìkìlọ̀ nípa Ìgbéraga

Open Bible reader