DaBible
Isaiah 63:6
Yoruba
Emi si tẹ̀ awọn enia mọlẹ ninu ibinu mi, mo si mu wọn mu yó ninu irunú mi, mo si mu ipa wọn sọkalẹ si ilẹ. Oore OLUWA sí Israẹli
English / KJV
And I will tread down the people in mine anger, and make them drunk in my fury, and I will bring down their strength to the earth.