Yoruba Bible
Isaiah 57:13
Nigbati iwọ ba kigbe, jẹ ki awọn ẹgbẹ rẹ ki o gbà ọ; ṣugbọn ẹfũfu ni yio gbá gbogbo wọn lọ; emi yio mu wọn kuro: ṣugbọn ẹniti o ba gbẹkẹ rẹ̀ le mi yio ni ilẹ na, yio si jogun oke mimọ́ mi. Ọlọrun Ṣe Ìlérí Ìrànlọ́wọ́ ati Ìwòsàn
Open Bible reader