Skip to content

Yoruba Bible

Isaiah 54:10

Nitori awọn oke-nla yio ṣi lọ, a o si ṣi awọn oke kékèké ni idi, ṣugbọn ore mi kì yio fi ọ silẹ, bẹ̃ni emi kì yio ṣi majẹmu alafia mi ni ipò: li Oluwa wi, ti o ṣãnu fun ọ. Ọjọ́ Iwájú Jerusalẹmu

Open Bible reader