Yoruba Bible
Isaiah 45:19
Emi kò sọrọ ni ikọkọ ni ibi okùnkun aiye: Emi kò wi fun iru-ọmọ Jakobu pe, Ẹ wá mi lasan: emi Oluwa li o nsọ ododo, mo fi nkan wọnni ti o tọ́ hàn. OLUWA Gbogbo Ayé ati Àwọn Oriṣa Babiloni
Open Bible readerYoruba Bible
Emi kò sọrọ ni ikọkọ ni ibi okùnkun aiye: Emi kò wi fun iru-ọmọ Jakobu pe, Ẹ wá mi lasan: emi Oluwa li o nsọ ododo, mo fi nkan wọnni ti o tọ́ hàn. OLUWA Gbogbo Ayé ati Àwọn Oriṣa Babiloni
Open Bible reader