Yoruba Bible
Isaiah 30:18
Nitorina ni Oluwa yio duro, ki o le ṣe ore fun nyin, ati nitori eyi li o ṣe ga, ki o le ṣe iyọ́nu si nyin: nitori Oluwa li Ọlọrun idajọ: ibukun ni fun gbogbo awọn ti o duro dè e. Ọlọrun Yóo Bukun Àwọn Eniyan Rẹ̀
Open Bible reader