Skip to content

Yoruba Bible

Isaiah 3:12

Niti awọn enia mi awọn ọmọde ni aninilara wọn, awọn obinrin si njọba wọn. A! enia mi, awọn ti nyẹ ọ si mu ọ ṣìna, nwọn si npa ipa-ọ̀na rẹ run. OLUWA Dá Àwọn Eniyan Rẹ̀ Lẹ́jọ́

Open Bible reader