Skip to content

Yoruba Bible

Haggai 2:9

Ogo ile ikẹhìn yi yio pọ̀ jù ti iṣãju lọ, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi: nihinyi li emi o si fi alafia fun ni, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi. Wolii náà Lọ Bá Àwọn Àlùfáà Jíròrò

Open Bible reader