Skip to content

Yoruba Bible

Haggai 1:11

Mo si ti pè ọdá sori ilẹ, ati sori oke-nla, ati sori ọkà ati sori ọti-waini titún, ati sori ororo, ati sori ohun ti ilẹ mu jade, ati sori enia, ati sori ẹran, ati sori gbogbo iṣẹ ọwọ ẹni. Àwọn Eniyan náà gbọ́ràn sí Àṣẹ OLUWA

Open Bible reader