Skip to content

DaBible

Genesis 50:14

Yoruba

Josefu si pada wá si Egipti, on ati awọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo awọn ti o bá a goke lọ lati sin baba rẹ̀, lẹhin ti o ti sin baba rẹ̀ tán. Josẹfu tún Dá Àwọn Arakunrin Rẹ̀ Lọ́kànle

English / KJV

And Joseph returned into Egypt, he, and his brethren, and all that went up with him to bury his father, after he had buried his father.

Download DaBible

Read online