Yoruba Bible
Genesisi 42:24
O si yipada kuro lọdọ wọn, o si sọkun; o si tun pada tọ̀ wọn wá, o si bá wọn sọ̀rọ, o si mú Ṣimeoni ninu wọn, o si dè e li oju wọn. Àwọn Arakunrin Josẹfu Pada sí Kenaani
Open Bible readerYoruba Bible
O si yipada kuro lọdọ wọn, o si sọkun; o si tun pada tọ̀ wọn wá, o si bá wọn sọ̀rọ, o si mú Ṣimeoni ninu wọn, o si dè e li oju wọn. Àwọn Arakunrin Josẹfu Pada sí Kenaani
Open Bible reader