DaBible
Genesis 19:11
Yoruba
Nwọn si bù ifọju lù awọn ọkunrin ti o wà li ẹnu-ọ̀na ile na, ati ewe ati àgba: bẹ̃ni nwọn dá ara wọn li agara lati ri ẹnu-ọ̀na. Lọti Jáde kúrò ní Sodomu
English / KJV
And they smote the men that were at the door of the house with blindness, both small and great: so that they wearied themselves to find the door.