Skip to content

Yoruba Bible

Esekieli 40:34

Awọn iloro rẹ̀ mbẹ nihà agbalá ode; igi ọpẹ si mbẹ lara atẹrigbà rẹ̀, nihà ìhin, ati nihà ọ̀hun: abagòke rẹ̀ si ní atẹ̀gun mẹjọ.

Open Bible reader