DaBible
Ezekiel 33:20
Yoruba
Sibẹ ẹnyin wi pe, Ọ̀na Oluwa kò dọgba, Ẹnyin ile Israeli, emi o dá olukuluku nyin li ẹjọ gẹgẹ bi ọ̀na rẹ̀.
English / KJV
Yet ye say, The way of the Lord is not equal. O ye house of Israel, I will judge you every one after his ways.