Yoruba Bible
Esekieli 31:18
Tani iwọ jọ li ogo ati ni titobi lãrin awọn igi Edeni? sibẹ a o mu ọ wá ilẹ pẹlu awọn igi Edeni si ìsalẹ aiye, iwọ o dubulẹ li ãrin awọn alaikọlà, pẹlu awọn ti a fi idà pa. Eyi ni Farao Esekieli ati gbogbo ọ̀pọlọpọ enia rẹ̀, li Oluwa Ọlọrun wi.
Open Bible reader