Skip to content

Yoruba Bible

Eksodu 6:13

OLUWA si bá Mose ati Aaroni sọ̀rọ, o si fi aṣẹ fun wọn si awọn ọmọ Israeli, ati si Farao, ọba Egipti, lati mú awọn ọmọ Israeli jade ni ilẹ Egipti. Àkọsílẹ̀ Ìran Mose ati Ti Aaroni

Open Bible reader