Skip to content

Yoruba Bible

Efesu 6:4

Ati ẹnyin baba, ẹ máṣe mu awọn ọmọ nyin binu: ṣugbọn ẹ mã tọ́ wọn ninu ẹkọ́ ati ikilọ Oluwa. Ẹrú ati Ọ̀gá

Open Bible reader