DaBible
Deuteronomy 7:11
Yoruba
Nitorina ki iwọ ki o pa ofin, ati ìlana, ati idajọ mọ́, ti mo palaṣẹ fun ọ li oni, lati ma ṣe wọn. Ibukun Tí Ó Wà ninu Ìgbọràn (Deut 28:1-14)
English / KJV
Thou shalt therefore keep the commandments, and the statutes, and the judgments, which I command thee this day, to do them.