Yoruba Bible
Deuteronomi 5:22
Ọ̀rọ wọnyi ni OLUWA sọ fun gbogbo ijọ nyin lori òke lati ãrin iná, awọsanma, ati lati inu òkunkun biribiri wá, pẹlu ohùn nla: kò si fi kún u mọ́. O si kọ wọn sara walã okuta meji, o si fi wọn fun mi. Ẹ̀rù Ba Àwọn Ọmọ Israẹli (Eks 20:18-21)
Open Bible reader