Skip to content

Yoruba Bible

Deuteronomi 31:8

Ati OLUWA on li o nlọ ṣaju rẹ; on ni yio pẹlu rẹ, on ki yio fi ọ silẹ, bẹ̃ni ki yio kọ̀ ọ: máṣe bẹ̀ru, bẹ̃ni ki àiya ki o máṣe fò ọ. Kíka Òfin ní Ọdún Keje-keje

Open Bible reader