Skip to content

Yoruba Bible

Deuteronomi 14:2

Nitoripe enia mimọ́ ni iwọ fun OLUWA Ọlọrun rẹ, OLUWA si ti yàn ọ lati ma ṣe enia ọ̀tọ fun ara rẹ̀, jù gbogbo orilẹ-ède lọ ti mbẹ lori ilẹ. Ẹran Tí Ó Mọ́ ati Èyí Tí Kò Mọ́ (Lef 11:1-47)

Open Bible reader