Yoruba Bible
Deuteronomi 1:8
Wò o, mo ti fi ilẹ na siwaju nyin: ẹ wọ̀ ọ lọ ki ẹ si gbà ilẹ na ti OLUWA bura fun awọn baba nyin, fun Abrahamu, fun Isaaki, ati fun Jakobu, lati fi fun wọn ati fun irú-ọmọ wọn lẹhin wọn. Mose Yan Àwọn Adájọ́ (Eks 18:13-27)
Open Bible reader