Yoruba Bible
Deuteronomi 1:33
Ti nlọ li ọ̀na ṣaju nyin, lati wá ibi fun nyin, ti ẹnyin o pagọ́ nyin si, ninu iná li oru, lati fi ọ̀na ti ẹnyin o gbà hàn nyin, ati ninu awọsanma li ọsán. OLUWA Jẹ Àwọn Ọmọ Israẹli Níyà (Num 14:20-45. )
Open Bible reader