Skip to content

Yoruba Bible

Danieli 7:8

Mo si kiyesi awọn iwo na, si wò o, iwo kekere miran kan si jade larin wọn, niwaju eyiti a fa mẹta tu ninu awọn iwo iṣaju: si kiyesi i, oju gẹgẹ bi oju enia wà lara iwo yi, ati ẹnu ti nsọ ohun nlanlà. Ìran Nípa Ẹni Ayérayé tó Jókòó lórí Ìtẹ́

Open Bible reader