Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 7:29

Mose si sá nitori ọ̀rọ yi, o si wa ṣe atipo ni ilẹ Midiani, nibiti o gbé bí ọmọ meji.

Open Bible reader