Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 24:16

Ninu eyi li emi si nṣe idaraya, lati ni ẹri-ọkàn ti kò li ẹ̀ṣẹ sipa ti Ọlọrun, ati si enia nigbagbogbo.

Open Bible reader