Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 19:6

Nigbati Paulu si gbe ọwọ́ le wọn, Ẹmí Mimọ́ si bà le wọn; nwọn si nfọ̀ ède miran, nwọn si nsọ asọtẹlẹ.

Open Bible reader