Skip to content

Yoruba Bible

2 Samuel 21:14

Nwọn si sin egungun Saulu ati ti Jonatani ọmọ rẹ̀ ni ilẹ Benjamini, ni Sela, ninu iboji Kiṣi baba rẹ̀: nwọn si ṣe gbogbo eyi ti ọba pa li aṣẹ: lẹhin eyini Ọlọrun si gbà ẹbẹ nitori ilẹ na. Wọ́n Bá Àwọn Òmìrán Filistini Jagun (1 Kron 20:4-8)

Open Bible reader