Skip to content

Yoruba Bible

2 Kings 2:18

Nwọn si tun pada tọ̀ ọ wá, (nitori ni Jeriko li o joko,) o wi fun wọn pe, Emi kò ti wi fun nyin pe, Ẹ máṣe lọ? Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Eliṣa

Open Bible reader