Skip to content

Yoruba Bible

2 Kings 18:12

Nitoriti nwọn kò gbà ohùn Oluwa Ọlọrun wọn gbọ́, ṣugbọn nwọn dà majẹmu rẹ̀, ati ohun gbogbo ti Mose iranṣẹ Oluwa pa li aṣẹ, nwọn kò si fi eti si wọn, bẹ̃ni nwọn kò si ṣe wọn. Asiria Halẹ̀ Mọ́ Jerusalẹmu (2 Kron 32:1-19; Ais 36:1-22)

Open Bible reader