Skip to content

Yoruba Bible

2 Corinthians 7:1

NITORINA, ẹnyin olufẹ, bi a ti ni ileri wọnyi, ẹ jẹ ki a wẹ̀ ara wa mọ́ kuro ninu gbogbo ẹgbin ti ara ati ti ẹmí, ki a mã sọ ìwa mimọ́ di pipé ni ìbẹru Ọlọrun. Inú Paulu Dùn Nígbà Tí Ìjọ Ronupiwada

Open Bible reader