Yoruba Bible
2 Corinthians 2:4
Nitoripe ninu ọ̀pọlọpọ wahalà ati arodun ọkan mi ni mo ti fi ọ̀pọlọpọ omije kọwe si nyin; kì iṣe nitori ki a le bà nyin ninu jẹ, ṣugbọn ki ẹnyin ki o le mọ̀ ifẹ ti mo ni si nyin lọpọlọpọ rekọja. Ẹ Dárí Ji Ẹni Tí Ó Ṣe Àìdára
Open Bible reader